
ORÍKÌ – Èdè Yorùbá Rẹwà
Jan 29, 2019 · ORÍKÌ Àsà kan pàtàkì tí àwa Omo Yorùbá ń gbé sonù báyìí ni àsà oríkì kíkì. Ní ilè Yorùbá kò sí nnkan náà tí kò ní oríkì yálà eranko , igi, ouñje , ìlú, èèyàn, bòròkìní, ìdílé tàbí orílẹ̀. Orísirísi ìdílé ni ó sì ní oríkì ti won. Kíni oríkì gan? Oríkì …
Èdè Yorùbá Rẹwà – A dá sílè fún àwọn ènìyàn tí wọn fẹ́ràn láti mò …
Jan 29, 2019 · A dá ojú ẹ̀ro àyélujára yí sílè fún àwọn ènìyàn tí wọn fẹ́ràn láti mò nípa èdè Yorùbá, àṣà àti ìṣe ilẹ̀ kóòtù ojire.
Àlọ́ Àpagbè – Ìjàpá Ati Ẹyẹ Àdàbà – Èdè Yorùbá Rẹwà
Jan 24, 2019 · Èyí ni Àlọ́ àpagbè fún gbogbo olólùfẹ́ ojú ìwé yìí, mọ lérò wípé ẹ ò gbádùn ẹ. Àlọ́ oooo Àlọ́ ọọọọ Àlọ́ yìí dá lórí Ìjàpá ati ẹyẹ Àdàbà Gégé Bí ẹ̀yin náà ti mọ̀, alàgàbàgebè ni Ìjàpá, olè àti ọ̀kánjúwà ni pẹ̀lú. Ní ayé àtijó, Ìjàpá àti Ẹyẹ Àdàbà jọ ń ṣe ọ̀rẹ́. Àdàbà ni ...
IGI Ọ̀PẸ – Èdè Yorùbá Rẹwà
Jan 28, 2019 · IGI Ọ̀PẸ Òjìji fì í Aró'gba aṣọ má balẹ̀ Èmi ọ̀pẹ ní jẹ́ bẹ́ẹ̀ Mo wúlò púpọ̀ fún ọmọ aráyé Àsàdànù kò sí nínú ẹ̀yà ara mi Igi mi wúlò fún afárá Lórí ìsun àti odò kékeré À ń fi imọ̀ mi kọ́lé Ọwọ́ ń bẹ lára mi Lèyí tí a fi ń jalè Ara mi ni àwọn akọ̀pe Tí ń da ẹmu Tó ni èròjà kojú o ...
ÌJÀPÁ ÀTI ÒGBÓJÚ ÒDE – Èdè Yorùbá Rẹwà
Jan 28, 2019 · Àlọ́ oooo Àlọ̀ ọọọọ Ọkunrin kan wa láyé àtijọ́, Ògbójú-ọdẹ ni, ṣùgbọ́n bi ó ti pa ẹran tó, kò fi dá nkan ṣe. Ọ̀pọ̀ igbà, ki ri ẹran ti ó bá pa tà, o ma ńpin fún ará ilú ni. Nigbati kò ri ẹran pa mọ́, ó di o Ọdẹ-apẹyẹ. Ni ọjọ kan, ògbójú-ọde yi ri ẹyẹ Òfú kan, ṣùgbọ́n ọta ibọn kan ṣoṣo ló ...
Oríkì Ìbejì – Èdè Yorùbá Rẹwà
Jan 24, 2019 · Oríkì Ìbejì: Wíníwíní lójú orogún Ejìwọ̀rọ̀ lojú ìyá ẹ̀, Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún, Ẹdúnjobí, ọmọ a gbórí igi rétẹréte, Ọkàn ń bá bí méjì ló wọlé tọ míwá, Ọ́bẹ́kíṣì bẹ́kéṣé, Ó bé sílé alákìísa, Ó salákìísà donígba aṣọ. Gbajúmọ̀ ọmọ tíí gbàkúnlẹ̀ ìyá, Tíí gbàdọ̀bálẹ̀ ...
ORÍ – Èdè Yorùbá Rẹwà
Jan 28, 2019 · ORÍ Orí àpéré àtété níran, Àtètè gbeni kù f'òsà, Orí mi gbèmí, Orí mi gbémi dé ibire, Orí mi gbémi dé ibi ayọ̀ mi, Ṣe bí orí ni gbéni taa dádé owó, Orí yìí kan náà ni gbéni taa wo èjìgbà'lẹ̀kẹ̀, Àtètè dáyé òkan t' ẹ̀gbọ́n,ẹni orí bá gbè ni sere, Bí orí bá gbeni wọn á ní olúwaarè ṣe Ògùn ni, Orí là bá bọ ká fi ...
KÍ LO RÍ L’Ọ́BẸ̀ TÍ Ó FI WAARO ỌWỌ́ – Èdè Yorùbá Rẹwà
Jan 29, 2019 · Ìtàn tí ó rò mó òwe Yorùbá yìí, Kí lo rí l'ọ́bẹ̀ tí fi waaro ọwọ́. Ní bí ọdún díè sẹ́yìn, ìlú kan wà tí wọ́n ń pè ní Kuo, ó wá ní Bode Saadu ni Ìpínlẹ̀ Kwara ṣùgbọ́n ìlú tí à ń sọ yìí jóná ni ọdún 1814. Gbogbo Yorùbá kó ló máa ń lo òwe yìí tẹ́lẹ̀, …
AṢỌ WÍWỌ – Èdè Yorùbá Rẹwà
Jan 29, 2019 · AṢỌ WÍWỌ Èèyàn lèyí ni àbí wèrè? Asínwín lèyí ni àbí abugije? Ṣé aṣọ lèyí abi kini? Ha! Ayé tí bàjé, Gbogbo ọmọ adáríhunrun tí sọ àṣà nù, A gbé òmíràn, A fi aṣọ sílè láìwọ̀, A sọ ìhòòhò rí rìn di ohun gidi, A rìn ìhòòhò nítorí oge, Kilode tí á lé wọṣọ iyì, Taa dáyé bá, Bí bùbá, sooro, agbádá ...
A B D Olówe – Èdè Yorùbá Rẹwà
A______ Àgbà kìí wà lọ́jà, k'órí ọmọ tuntun ó wó. B______ Bá mi na ọmọ mi, kò dénu ọlọ́mọ. D______ Dídà ló dà l'ọmọ dé ẹ̀gbẹ́, ẹ̀gbẹ́ kìí ṣe ilé ọmọ. E_____ Ènìyàn ló ń bẹ nìdí oró l’oró ń ké. Ẹ____Ẹ̀dá tó mo ìṣe òkùnkùn, kó má ṣe d'òṣùpá l'oró F_____ Fálànà gbọ́ tìẹ , t’ara eni làá ...